Jẹ́nẹ́sísì 7:23 BMY

23 Gbogbo ohun alààyè tí ó wà lórí ilẹ̀ ayé ni a parẹ́: ènìyàn àti ẹranko, àwọn ohun tí ń rìn nílẹ̀, àwọn ẹyẹ ojú ọ̀run pátapáta ló ṣègbé. Nóà àti àwọn tí ó wà pẹ̀lú rẹ̀ nínú ọkọ̀ ni ó ṣẹ́kù.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 7

Wo Jẹ́nẹ́sísì 7:23 ni o tọ