Jẹ́nẹ́sísì 7:3 BMY

3 Sì mú méjeméje pẹ̀lú nínú onírúurú ẹyẹ takọ tabo ni kí o mú wọn, wọlé sínú ọkọ̀ pẹ̀lú rẹ, kí á baà lè pa wọ́n mọ́ láàyè ní gbogbo ayé.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 7

Wo Jẹ́nẹ́sísì 7:3 ni o tọ