Jẹ́nẹ́sísì 8:1 BMY

1 Ọlọ́run sì rántí Nóà àti ohun alààyè gbogbo tí ó wà pẹ̀lú rẹ̀, bí àwọn ẹranko igbó àti ohun ọ̀sìn, ó sì mú kí afẹ́fẹ́ fẹ́ sórí ilẹ̀, omi náà sì fà.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 8

Wo Jẹ́nẹ́sísì 8:1 ni o tọ