Jẹ́nẹ́sísì 8:22 BMY

22 “Níwọ̀n ìgbà tí ayé bá sì wà,ìgbà ọ̀gbìn àti ìgbà ìkórèìgbà òtútù àti ìgbà ooru,igbà ẹ̀ẹ̀rùn àti ìgbà òjò,ìgbà ọ̀ṣán àti ìgbà òru,yóò wà títí láé.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 8

Wo Jẹ́nẹ́sísì 8:22 ni o tọ