Jẹ́nẹ́sísì 8:9 BMY

9 Ṣùgbọ́n àdàbà náà kò rí ìyàngbẹ ilẹ̀ bà lé nítorí omi kò tí ì tan lórí ilẹ̀, ó sì padà sọ́dọ̀ Nóà. Nóà na ọwọ́ rẹ̀ jáde ó sì mú ẹyẹ náà wọlé sọ́dọ̀ ara rẹ̀ nínú ọkọ̀.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 8

Wo Jẹ́nẹ́sísì 8:9 ni o tọ