Jẹ́nẹ́sísì 9:21 BMY

21 Ó mu àmupara nínú ọtí wáìnì àjàrà rẹ̀, ó sì tú ara rẹ̀ sí ìhòòhò, ó sì sùn nínú àgọ́ rẹ̀.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 9

Wo Jẹ́nẹ́sísì 9:21 ni o tọ