Jẹ́nẹ́sísì 9:23 BMY

23 Ṣùgbọ́n Ṣémù àti Jáfétì mú aṣọ lé èjìká wọn, wọ́n sì fi ẹ̀yìn rìn, wọ́n sì bo ìhòòhò baba wọn. Wọ́n kọjú ṣẹ́yìn kí wọn kí ó má ba à rí ìhòòhò baba wọn.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 9

Wo Jẹ́nẹ́sísì 9:23 ni o tọ