Jẹ́nẹ́sísì 9:3 BMY

3 Gbogbo ohun tó wà láàyè tí ó sì ń rìn, ni yóò jẹ́ oúnjẹ fún-ún yín bí mo ṣe fi ewéko fún un yín, náà ni mo fi ohun gbogbo fún un yín.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 9

Wo Jẹ́nẹ́sísì 9:3 ni o tọ