Jẹ́nẹ́sísì 1:21 BMY

21 Nítorí náà Ọlọ́run dá àwọn ẹ̀dá alààyè ńlá-ńlá sí inú òkun, àwọn ohun ẹlẹ́mìí àti àwọn ohun tí ń rìn ní onírúurú tiwọn, àti àwọn ẹyẹ abìyẹ́ ní onírúurú tiwọn. Ọlọ́run sì rí i pé ó dára.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 1

Wo Jẹ́nẹ́sísì 1:21 ni o tọ