Jẹ́nẹ́sísì 1:22 BMY

22 Ọlọ́run súre fún wọn, ó sì wí pé, “Ẹ máa bí sí i, ẹ sì máa pọ̀ sí i, ẹ kún inú omi òkun, kí àwọn ẹyẹ náà sì máa pọ̀ sí i ní orí ilẹ̀.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 1

Wo Jẹ́nẹ́sísì 1:22 ni o tọ