Jẹ́nẹ́sísì 12:4 BMY

4 Bẹ́ẹ̀ ni Ábúrámù lọ bí Olúwa ti sọ fún un. Lọ́tì náà sì bá a lọ. Ábúrámù jẹ́ ẹni àrùndínlọ́gọ́rin (75) ọdún nígbà tí ó jáde kúrò ní Háránì.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 12

Wo Jẹ́nẹ́sísì 12:4 ni o tọ