Jẹ́nẹ́sísì 12:5 BMY

5 Ábúrámù sì mú Ṣáráì aya rẹ̀, àti Lọ́tì ọmọ arákùnrin rẹ̀: gbogbo ohun ìní tí wọ́n ti kó jọ àti àwọn ènìyàn tí wọ́n ní ní Háránì. Wọ́n sì jáde lọ sí ilẹ̀ Kénánì. Wọ́n sì gúnlẹ̀ ṣíbẹ̀.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 12

Wo Jẹ́nẹ́sísì 12:5 ni o tọ