Jẹ́nẹ́sísì 13:10 BMY

10 Lọ́tì sì gbójú sókè, ó sì ri wí pé gbogbo pẹ̀tẹ́lẹ̀ Jọ́dánì ni omi rin dáradára bí ọgbà Olúwa, bí ilẹ̀ Éjíbítì, ní ọ̀nà Ṣóárì. (Èyí ní ìṣáájú kí Olúwa tó pa Ṣódómù àti Gòmórà run).

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 13

Wo Jẹ́nẹ́sísì 13:10 ni o tọ