Jẹ́nẹ́sísì 13:11 BMY

11 Nítorí náà Lọ́tì yan gbogbo pẹ̀tẹ́lẹ̀ Jọ́dánì yìí fún ara rẹ̀, ó sì ń lọ sí ọ̀nà ìlà oòrùn. Òun àti Ábúrámù sì pínyà.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 13

Wo Jẹ́nẹ́sísì 13:11 ni o tọ