Jẹ́nẹ́sísì 13:14 BMY

14 Olúwa sì wí fún Ábúrámù lẹ́yìn ìpínyà òun àti Lọ́tí pé, “Gbé ojú rẹ sókè níṣinṣin yìí, kí o sì wò láti ibi tí o gbé wà a nì lọ sí ìhà àríwá àti sí ìhà gúsù, sí ìlà oòrùn àti sí ìwọ̀ rẹ̀.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 13

Wo Jẹ́nẹ́sísì 13:14 ni o tọ