Jẹ́nẹ́sísì 14:12 BMY

12 Wọ́n sì mú Lọ́tì ọmọ arákùnrin Ábúrámù tí ń gbé ní Ṣódómù àti gbogbo ohun-ìní rẹ̀.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 14

Wo Jẹ́nẹ́sísì 14:12 ni o tọ