Jẹ́nẹ́sísì 14:13 BMY

13 Ẹnìkan tí ó sá àsálà sì wá ròyìn fún Ábúrámù, ará Ébérù. Ábúrámù sá ti tẹ̀dó sí igbó igi Óákù tí ó jẹ́ ti Mámúrè ará Ámórì, arákùnrin Ésíkólì àti Ánérì: àwọn ẹni tí ó ń bá Ábúrámù ní àṣepọ̀.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 14

Wo Jẹ́nẹ́sísì 14:13 ni o tọ