Jẹ́nẹ́sísì 15:4 BMY

4 Ọ̀rọ̀ Olúwa sì tún tọ̀ ọ́ wá pé: “Ọkùnrin yìí kọ́ ni yóò jẹ́ àrólé (ajogún) rẹ bí kò ṣe ọmọ tí ìwọ bí fúnrarẹ ni yóò jẹ́ àrólé rẹ.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 15

Wo Jẹ́nẹ́sísì 15:4 ni o tọ