Jẹ́nẹ́sísì 15:5 BMY

5 Olúwa sì mú Ábúrámù jáde síta ó sì wí fún un pé, “Gbójú sókè sí ọ̀run kí o sì ka àwọn ìràwọ̀-bí ó bá ṣe pé ìwọ le è kà wọ́n.” Ó sì wí fun un pé, “Nítorí náà, báyìí ni irú ọmọ rẹ yóò rí.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 15

Wo Jẹ́nẹ́sísì 15:5 ni o tọ