Jẹ́nẹ́sísì 16:1 BMY

1 Ṣáráì, aya Ábúrámù kò bímọ fún un, ṣùgbọ́n ó ní ọmọ ọ̀dọ̀ obìnrini ará Éjíbítì kan tí ń jẹ́ Ágárì.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 16

Wo Jẹ́nẹ́sísì 16:1 ni o tọ