Jẹ́nẹ́sísì 16:2 BMY

2 Nítorí náà, Ṣáráì wí fún Ábúrámù pé, “Kíyèsí i Olúwa ti sé mi ní inú, èmi kò sì bímọ, wọlé tọ ọmọ ọ̀dọ̀ mi lọ, bóyá èmi yóò le ti ipaṣẹ̀ rẹ̀ ní ọmọ.”Ábúrámù sì gba ohun tí Ṣáráì sọ.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 16

Wo Jẹ́nẹ́sísì 16:2 ni o tọ