Jẹ́nẹ́sísì 17:27 BMY

27 Àti gbogbo ọkùnrin tí ó wà ní ilé Ábúráhámù, ìbá à ṣe èyí tí a bí ní ilé rẹ̀ tàbí èyí tí a fi owó rà lọ́wọ́ àlejò ni a kọ ní ílà pẹ̀lú rẹ̀.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 17

Wo Jẹ́nẹ́sísì 17:27 ni o tọ