Jẹ́nẹ́sísì 18:10 BMY

10 Nígbà náà ni Olúwa wí fún un pé, “Ṣárà aya rẹ yóò sì bí ọmọkùnrin kan.”Sárà sì ń dẹtí gbọ́ láti ẹnu ọ̀nà àgọ́ tí ó wà lẹ́yìn wọn.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 18

Wo Jẹ́nẹ́sísì 18:10 ni o tọ