Jẹ́nẹ́sísì 20:8 BMY

8 Ní òwúrọ̀ kùtùkùtù ọjọ́ kejì, Ábímélékì pe gbogbo àwọn ìjòyè rẹ̀. Nígbà tí ó sì ṣọ gbogbo ohun tí ó sẹlẹ̀ fún wọn, ẹ̀rù bà wọ́n gidigidi.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 20

Wo Jẹ́nẹ́sísì 20:8 ni o tọ