Jẹ́nẹ́sísì 20:7 BMY

7 Níṣinyìí, dá aya ọkùnrin náà padà, nítorí pé wòlíì ni, yóò sì gbàdúrà fún ọ, ìwọ yóò sì yè. Ṣùgbọ́n bí ìwọ kò bá dá a padà, mọ̀ dájú pé ìwọ àti gbogbo ẹni tíí ṣe tìrẹ yóò kú.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 20

Wo Jẹ́nẹ́sísì 20:7 ni o tọ