Jẹ́nẹ́sísì 21:25 BMY

25 Nígbà náà ni Ábúráhámù fi ẹ̀dùn ọkàn rẹ̀ hàn fún Ábímélékì nípa kànga tí àwọn ọmọ-ọ̀dọ̀ rẹ̀ gbà lọ́wọ́ rẹ̀.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 21

Wo Jẹ́nẹ́sísì 21:25 ni o tọ