Jẹ́nẹ́sísì 21:26 BMY

26 Ṣùgbọ́n Ábímélékì dáhùn pé, “Èmi kò mọ ẹni tí ó ṣe èyí, ìwọ kò sì sọ fún mi tẹ́lẹ̀, òní ni mo sẹ̀sẹ̀ ń gbọ́ báyìí.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 21

Wo Jẹ́nẹ́sísì 21:26 ni o tọ