Jẹ́nẹ́sísì 22:1 BMY

1 Nígbà tí ó ṣe, Ọlọ́run dán Ábúráhámù wò, ó pè é, ó sì wí pé, “Ábúráhámù.”Ábúráhámù sì dáhùn pé, “Èmi nìyí.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 22

Wo Jẹ́nẹ́sísì 22:1 ni o tọ