Jẹ́nẹ́sísì 22:2 BMY

2 Ọlọ́run sì wí pé, “Mú ọmọ rẹ, àní Ísáakì ọmọ rẹ kan ṣoṣo o nì, tí ìwọ fẹ́ràn, lọ sí ilẹ̀ Móráyà, kí o sì fi rúbọ ṣíṣun níbẹ̀ lórí ọ̀kan nínú àwọn òkè tí èmi yóò sọ fún ọ”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 22

Wo Jẹ́nẹ́sísì 22:2 ni o tọ