Jẹ́nẹ́sísì 22:7 BMY

7 Ísáákì sì sọ fún Ábúráhámù baba rẹ̀ wí pé, “Baba mi.”Ábúráhámù sì da lóhùn pé, “Èmi nìyí ọmọ mi.”Ísáákì sì tún wí pé, “Wò ó iná àti igi nìyí, ṣùgbọ́n níbo ni ọ̀dọ́ àgùntàn fún ẹbọ sísun náà wà?”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 22

Wo Jẹ́nẹ́sísì 22:7 ni o tọ