Jẹ́nẹ́sísì 22:8 BMY

8 Ábúráhámù sì dáhùn pé, “Ọmọ mi, Ọlọ́run fúnra rẹ̀ ni yóò pèsè ọ̀dọ̀-àgùntàn fún ẹbọ sísun náà.” Bẹ́ẹ̀ ni àwọn méjèèjì tẹ̀ṣíwájú nínú ìrìn-àjò wọn.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 22

Wo Jẹ́nẹ́sísì 22:8 ni o tọ