Jẹ́nẹ́sísì 23:16 BMY

16 Ábúráhámù sì gba ohun tí Éfúróni wí, ó sì wọn iye owó fàdákà náà lójú gbogbo ènìyàn: irínwó owó idẹ fàdákà gẹ́gẹ́ bí ìwọ̀n oníṣòwò ayé ìgbà náà.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 23

Wo Jẹ́nẹ́sísì 23:16 ni o tọ