Jẹ́nẹ́sísì 23:17 BMY

17 Báyìí ni ilẹ̀ Éfúrónì tí ó wà ni Mákípélà nítòòsí Mámúrè-ilẹ̀ náà àti ihò àpáta tí ó wà nínú rẹ̀ àti gbogbo igi tí ó wà nínú ilẹ̀ náà ni a ṣe ètò rẹ̀ dájú,

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 23

Wo Jẹ́nẹ́sísì 23:17 ni o tọ