Jẹ́nẹ́sísì 24:21 BMY

21 Láì sọ ọ̀rọ̀ kan, ìránṣẹ́ yìí ń wo ọmọbìnrin náà fínnífínní láti mọ̀ bóyá Ọlọ́run ti ṣe ìrìn-àjò òun ní rere tàbí bẹ́ẹ̀ kọ́.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 24

Wo Jẹ́nẹ́sísì 24:21 ni o tọ