Jẹ́nẹ́sísì 24:22 BMY

22 Lẹ́yìn tí àwọn ràkunmí náà ti mu omi tán, ni ọkùnrin náà mú òrùka wúrà ààbọ̀ ìwọn sékélì àti júfù méjì fún ọwọ́ rẹ̀, tí ìwọ̀n sékélì wúrà mẹ́wàá.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 24

Wo Jẹ́nẹ́sísì 24:22 ni o tọ