Jẹ́nẹ́sísì 27:40 BMY

40 Nípa idà ni ìwọ yóò máa gbé,ìwọ yóò sì máa sin àbúrò rẹ,ṣùgbọ́n ní ìkẹyìn, nígbà tí ìwọ bá di alágbáraìwọ yóò já àjàgà rẹ̀-kúrò lọ́rùn rẹìwọ yóò sì di òmìnira.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 27

Wo Jẹ́nẹ́sísì 27:40 ni o tọ