Jẹ́nẹ́sísì 27:41 BMY

41 Ísọ̀ sì kóríra Jákọ́bù nítorí ìre tí baba rẹ̀ sú fún un, ó sì wí fún ara rẹ̀ pé, “Baba mi ṣáà ti fẹ́rẹ̀ẹ́ kú, nígbà náà ni èmi ó pa Jákọ́bù, arákùnrin mi.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 27

Wo Jẹ́nẹ́sísì 27:41 ni o tọ