Jẹ́nẹ́sísì 28:11 BMY

11 Nígbà tí ó dé ibìkan, ó dúró ní òru náà nítorí tí ilẹ̀ ti ń sú, ó sì gbé òkúta kan ó fi ṣe ìrọ̀rí, ó sì sùn.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 28

Wo Jẹ́nẹ́sísì 28:11 ni o tọ