Jẹ́nẹ́sísì 28:12 BMY

12 Ó sì lá àlá pé, a gbé àkàsọ̀ kan dúró ti ó fi ìdí lélẹ̀, orí rẹ̀ sì kan ọ̀run, àwọn ańgẹ́lì Ọlọ́run sì ń gòkè, wọ́n sì ń sọ̀kalẹ̀ lórí rẹ̀.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 28

Wo Jẹ́nẹ́sísì 28:12 ni o tọ