Jẹ́nẹ́sísì 29:5 BMY

5 Ó sì bi wọ́n pé, “Ǹjẹ́ ẹ mọ Lábánì ọmọ-ọmọ Náhórì?”Wọ́n sì dáhùn pé, “Bẹ́ẹ̀ ni, àwa mọ̀ ọ́n.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 29

Wo Jẹ́nẹ́sísì 29:5 ni o tọ