Jẹ́nẹ́sísì 29:6 BMY

6 Jákọ́bù béèrè pé, “Ṣe àlàáfíà ni ó wà?”Wọ́n sì dáhùn pé, “Bẹ́ẹ̀ ni, àlàáfíà ni. Wò ó, Rákélì ọmọ rẹ̀ ni ó ń bọ̀ yìí pẹ̀lú agbo àgùntàn.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 29

Wo Jẹ́nẹ́sísì 29:6 ni o tọ