Jẹ́nẹ́sísì 3:7 BMY

7 Nígbà náà ni ojú àwọn méjèèjì sì là, wọ́n sì mọ̀ pé àwọn wà ní ìhòòhò; wọ́n sì rán ewé ọ̀pọ̀tọ́ pọ̀, wọ́n sì fi bo ara wọn.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 3

Wo Jẹ́nẹ́sísì 3:7 ni o tọ