Jẹ́nẹ́sísì 3:8 BMY

8 Nígbà náà ni ọkùnrin náà àti aya rẹ̀ gbọ́ ìró Olúwa Ọlọ́run bí ó ti ń rìn nínú ọgbà nígbà tí ojú ọjọ́ tura, wọ́n sì fi ara pamọ́ kúrò níwájú Olúwa Ọlọ́run sí àárin àwọn igi inú ọgbà.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 3

Wo Jẹ́nẹ́sísì 3:8 ni o tọ