Jẹ́nẹ́sísì 32:32 BMY

32 Ìdí nìyí tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì kì í fií jẹ iṣan tí ó wà ní ọ̀ọ́kán ibi tí eegun itan ti bẹ̀rẹ̀ títí di òní-olónìí, nítorí níbi iṣan náà ni a ti fọwọ́ kan ibi tí egungun itan Jákọ́bù ti bẹ̀rẹ̀.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 32

Wo Jẹ́nẹ́sísì 32:32 ni o tọ