Jẹ́nẹ́sísì 33:1 BMY

1 Jákọ́bù sì gbójú sókè, ó sì rí Ísọ̀ àti irinwó ọkùnrin tí wọ́n ń bọ̀, ó sì pín àwọn ọmọ fún Líà, Rákélì àti àwọn ìránṣẹ́bìnrin méjèèjì.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 33

Wo Jẹ́nẹ́sísì 33:1 ni o tọ