Jẹ́nẹ́sísì 33:2 BMY

2 Ó sì ti àwọn ìránṣẹ́bìnrin àti àwọn ọmọ wọn ṣíwájú, Líà àti àwọn ọmọ rẹ̀ sì jẹ ọ̀wọ́ kejì tí ó tẹ̀lé wọn, Rákélì àti Jóṣẹ́fù sì wà lẹ́yìn pátapáta.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 33

Wo Jẹ́nẹ́sísì 33:2 ni o tọ