Jẹ́nẹ́sísì 33:3 BMY

3 Jákọ́bù fúnra rẹ̀ wa lọ ṣíwájú pátapáta, ó sì tẹríba ní ìgbà méje bí ó ti ń sún mọ́ Ísọ̀, arákùnrin rẹ̀.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 33

Wo Jẹ́nẹ́sísì 33:3 ni o tọ