Jẹ́nẹ́sísì 35:3 BMY

3 Nígbà náà ni kí ẹ wá, kí ẹ jẹ́ kí a lọ sí Bẹ́tẹ́lì, níbi tí n ó ti mọ pẹpẹ fún Ọlọ́run, tí ó dá mi lóhùn ní ọjọ́ ìpọ́njú mi tí ó sì ti ń pẹ̀lú mi níbi gbogbo tí mo ń lọ.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 35

Wo Jẹ́nẹ́sísì 35:3 ni o tọ