Jẹ́nẹ́sísì 35:4 BMY

4 Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n fún Jákọ́bù ní gbogbo àjòjì òrìsà tí ó wà lọ́wọ́ wọn, àti yẹtí etí wọn, Jákọ́bù sì bo gbogbo wọn mọ́lẹ̀ sabẹ́ igi Óákù ní Ṣékémù.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 35

Wo Jẹ́nẹ́sísì 35:4 ni o tọ