Jẹ́nẹ́sísì 35:5 BMY

5 Wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ ìrìn-àjò wọn. Ìbẹ̀rù láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run sì ń bá lé gbogbo ìlú tí wọ́n ń là kọjá ní ọ̀nà wọn tó bẹ́ẹ̀ tí kò sí ẹni tí ó le è dojú ìjà kọ wọ́n.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 35

Wo Jẹ́nẹ́sísì 35:5 ni o tọ